Ìṣe Àwọn Aposteli 22:11 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò lè ríran mọ́ nítorí ìmọ́lẹ̀ náà mọ́lẹ̀ pupọ. Àwọn ẹni tí ó wà pẹlu mi bá fà mí lọ́wọ́ lọ sí Damasku.

Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:1-12