Ìṣe Àwọn Aposteli 22:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá bèèrè pé, ‘Kí ni kí n ṣe Oluwa?’ Oluwa bá dá mi lóhùn pé, ‘Dìde kí o máa lọ sí Damasku. Níbẹ̀ a óo sọ fún ọ gbogbo nǹkan tí a ti ṣètò fún ọ láti ṣe.’

Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:7-12