Ìṣe Àwọn Aposteli 22:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọ́n wà pẹlu mi rí ìmọ́lẹ̀ náà, ṣugbọn wọn kò gbọ́ ohùn ẹni tí ó ń bá mi sọ̀rọ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:2-14