Ìṣe Àwọn Aposteli 22:12 BIBELI MIMỌ (BM)

“Lẹ́yìn náà ni ọkunrin kan tí ń jẹ́ Anania dé. Ó jẹ́ olùfọkànsìn nípa ti Òfin Mose; gbogbo àwọn ẹni tí ń gbé Judia ni wọ́n sì jẹ́rìí rere nípa rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Ìṣe Àwọn Aposteli 22:4-15