Ìṣe Àwọn Aposteli 20:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ máa ṣọ́ra. Ẹ ranti pé fún ọdún mẹta, tọ̀sán-tòru ni n kò fi sinmi láti máa gba ẹnìkọ̀ọ̀kan yín níyànjú pẹlu omi lójú.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:24-34