Ìṣe Àwọn Aposteli 20:32 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nisinsinyii, mo fi yín lé Ọlọrun lọ́wọ́ ati ọ̀rọ̀ oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀ tí ó lè mu yín dàgbà, tí ó sì lè fun yín ní ogún pẹlu gbogbo àwọn tí a ti sọ di mímọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:31-38