Ìṣe Àwọn Aposteli 20:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo mọ̀ pé láàrin yín àwọn ẹlòmíràn yóo dìde tí wọn yóo fi irọ́ yí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu lọ́kàn pada láti tẹ̀lé wọn.

Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Ìṣe Àwọn Aposteli 20:22-34