Ìṣe Àwọn Aposteli 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n gbọ́ ìró yìí, àwọn eniyan rọ́ wá. Ẹnu yà wọ́n nítorí ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn gbọ́ tí wọn ń sọ èdè tirẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:1-13