Ìṣe Àwọn Aposteli 2:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò náà, àwọn Juu tí wọ́n jẹ́ olùfọkànsìn ti gbogbo orílẹ̀-èdè ayé wá, wọ́n wà ní Jerusalẹmu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:1-8