Ìṣe Àwọn Aposteli 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn bá kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí sọ oríṣìíríṣìí èdè mìíràn gẹ́gẹ́ bí Ẹ̀mí ti fi fún wọn láti máa sọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:1-14