Ìṣe Àwọn Aposteli 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí dà wọ́n láàmú, ó sì yà wọ́n lẹ́nu. Wọ́n ní, “Ṣebí ará Galili ni gbogbo àwọn tí ó ń sọ̀rọ̀ wọnyi?

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:1-13