Ìṣe Àwọn Aposteli 2:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń fi ọkàn kan lọ sí Tẹmpili lojoojumọ. Wọ́n jọ ń jẹun láti ilé dé ilé. Wọ́n jọ ń jẹun pẹlu ayọ̀ ati pẹlu ọkàn kan.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:40-47