Ìṣe Àwọn Aposteli 2:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ta gbogbo ohun tí wọ́n ní, wọ́n sì pín owó tí wọ́n rí láàrin ara wọn, gẹ́gẹ́ bí ẹnìkọ̀ọ̀kan ti ṣe aláìní sí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:41-47