Ìṣe Àwọn Aposteli 2:47 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń fi ìyìn fún Ọlọrun. Gbogbo àwọn eniyan ni ó fẹ́ràn wọn. Lojoojumọ ni àwọn tí wọ́n rí ìgbàlà ń dara pọ̀ mọ́ wọn.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:38-47