Ìṣe Àwọn Aposteli 2:41 BIBELI MIMỌ (BM)

A ṣe ìrìbọmi fún àwọn tí wọ́n gba ọ̀rọ̀ náà. Ní ọjọ́ náà àwọn ẹgbẹẹdogun (3,000) eniyan ni a kà kún ọmọ ìjọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:32-46