Ìṣe Àwọn Aposteli 2:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń fi tọkàntọkàn kọ́ ẹ̀kọ́ tí àwọn aposteli ń kọ́ wọn; wọ́n wà ní ìrẹ́pọ̀, wọ́n jọ ń jẹun; wọ́n jọ ń gbadura.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:35-45