Ìṣe Àwọn Aposteli 2:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún bá wọn sọ̀rọ̀ pupọ, ó ń rọ̀ wọ́n gidigidi, pé, “Ẹ gba ara yín kúrò ninu ìyà tí ìran burúkú yìí yóo jẹ.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:32-45