Ìṣe Àwọn Aposteli 2:29 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ̀yin ará, mo sọ fun yín láìṣe àní-àní pé Dafidi baba-ńlá wa kú, a sì sin ín; ibojì rẹ̀ wà níhìn-ín títí di òní.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:28-30