Ìṣe Àwọn Aposteli 2:28 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti fi ọ̀nà ìyè hàn mí,O óo sì fi ayọ̀ kún ọkàn mi níwájú rẹ.’

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:18-31