Ìṣe Àwọn Aposteli 2:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nítorí ó jẹ́ aríran, ó sì mọ̀ pé Ọlọrun ti búra fún òun pé ọ̀kan ninu ọmọ tí òun óo bí ni yóo jókòó lórí ìtẹ́ òun,

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:25-39