Ìṣe Àwọn Aposteli 2:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Dafidi sọ nípa rẹ̀ pé,‘Mo rí Oluwa níwájú mi nígbà gbogbo,ó wà ní ọwọ́ ọ̀tún minítorí náà ohunkohun kò lè dà mí láàmú.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:22-32