Ìṣe Àwọn Aposteli 2:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Ọlọrun tú ìdè ikú, ó jí i dìde ninu òkú! Kò jẹ́ kí ikú ní agbára lórí rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:14-27