Ìṣe Àwọn Aposteli 2:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà inú mi dùn, mo bú sẹ́rìn-ín.Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé eniyan ẹlẹ́ran-ara ni mí,sibẹ n óo gbé ìgbé-ayé mi pẹlu ìrètí;

Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Ìṣe Àwọn Aposteli 2:24-27