Ìṣe Àwọn Aposteli 18:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Kirisipu, ẹni tí ń darí ètò ilé ìpàdé àwọn Juu gba Oluwa gbọ́ pẹlu gbogbo ilé rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni pupọ ninu àwọn ará Kọrinti; nígbà tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ Oluwa, wọ́n gbàgbọ́, wọ́n bá ṣe ìrìbọmi.

Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:1-15