Ìṣe Àwọn Aposteli 18:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni ó bá kúrò níbẹ̀, ó wọ ilé ẹnìkan tí ó ń jẹ́ Titiu Jusitu, ẹnìkan tí ń sin Ọlọrun. Ilé rẹ̀ fẹ̀gbẹ́kẹ̀gbẹ́ pẹlu ilé ìpàdé àwọn Juu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:1-11