Ìṣe Àwọn Aposteli 18:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní alẹ́ ọjọ́ kan, Paulu rí ìran kan. Ninu ìran náà Oluwa sọ fún un pé, “Má bẹ̀rù, máa waasu, má dákẹ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Ìṣe Àwọn Aposteli 18:8-19