Ìṣe Àwọn Aposteli 15:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gba Siria ati Silisia kọjá, ó ń mú àwọn ìjọ lọ́kàn le.

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:35-41