Ìṣe Àwọn Aposteli 16:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Paulu dé Dabe ati Listira. Onigbagbọ kan tí ń jẹ́ Timoti wà níbẹ̀. Ìyá rẹ̀ jẹ́ Juu tí ó gba Jesu gbọ́; ṣugbọn Giriki ni baba rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Ìṣe Àwọn Aposteli 16:1-5