Ìṣe Àwọn Aposteli 15:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Paulu mú Sila ó bá ọ̀nà tirẹ̀ lọ lẹ́yìn tí àwọn onigbagbọ ti fi í lé oore-ọ̀fẹ́ Oluwa lọ́wọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Ìṣe Àwọn Aposteli 15:34-41