Ìṣe Àwọn Aposteli 13:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀mí Mímọ́ bá gbé Saulu, tí a tún ń pè ní Paulu. Ó tẹjú mọ́ onídán náà,

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:2-13