Ìṣe Àwọn Aposteli 13:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Elimasi, tí ìtumọ̀ orúkọ rẹ̀ jẹ́ onídán, takò wọ́n. Ó ń wá ọ̀nà láti yí ọkàn gomina pada kúrò ninu igbagbọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:1-16