Ìṣe Àwọn Aposteli 13:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin yìí ń ṣiṣẹ́ lọ́dọ̀ gomina ilẹ̀ náà, tí ń jẹ́ Segiu Paulu. Gomina yìí jẹ́ olóye eniyan. Ó ranṣẹ pe Banaba ati Saulu nítorí ó fẹ́ gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọrun.

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:3-17