Ìṣe Àwọn Aposteli 13:10 BIBELI MIMỌ (BM)

ó ní, “Ìwọ yìí, tí ó jẹ́ kìkì oríṣìíríṣìí ẹ̀tàn ati ìwà burúkú! Ìwọ ọmọ èṣù yìí! Ọ̀tá gbogbo nǹkan tí ó dára! O kò ní yé yí ọ̀nà títọ́ Oluwa po!

Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Ìṣe Àwọn Aposteli 13:9-11