Ìṣe Àwọn Aposteli 12:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni Peteru bá tẹ̀lé e jáde. Kò mọ̀ pé òtítọ́ ni ohun tí ó ti ọwọ́ angẹli náà ṣẹlẹ̀, ó ṣebí àlá ni.

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:2-19