Ìṣe Àwọn Aposteli 12:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli náà sọ fún un pé, “Di ìgbànú rẹ, sì wọ sálúbàtà rẹ.” Peteru bá ṣe bí angẹli náà ti wí. Angẹli yìí tún sọ fún un pé, “Da aṣọ rẹ bora, kí o máa tẹ̀lé mi.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:1-10