Ìṣe Àwọn Aposteli 12:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kọjá ẹ̀ṣọ́ kinni ati ekeji, wọ́n wá dé ẹnu ọ̀nà ńlá onírin tí ó jáde sinu ìlú. Fúnra ìlẹ̀kùn yìí ni ó ṣí sílẹ̀ fún wọn. Wọ́n bá jáde sí ojú ọ̀nà kan. Lójú kan náà, angẹli bá rá mọ́ Peteru lójú.

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:1-20