Ìṣe Àwọn Aposteli 12:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó gbọ́ ohùn Peteru, inú rẹ̀ dùn tóbẹ́ẹ̀ tí kò fi dúró ṣí ìlẹ̀kùn; ṣugbọn ó sáré lọ sinu ilé, ó lọ sọ pé Peteru wà lóde lẹ́nu ọ̀nà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:4-18