Ìṣe Àwọn Aposteli 12:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí bú u pé, “Orí rẹ dàrú!” Ṣugbọn ó ṣá tẹnumọ́ ọn pé bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ rí. Wọ́n wá sọ pé, “A jẹ́ pé angẹli rẹ̀ ni!”

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:9-21