Ìṣe Àwọn Aposteli 12:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Peteru kan ìlẹ̀kùn tí ó wà lójúde, ọdọmọbinrin kan tí ń jẹ́ Roda wá láti ṣí i.

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:10-22