Ìṣe Àwọn Aposteli 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí àwọn kan ninu àwọn ará Kipru ati Kirene dé Antioku, wọ́n bá àwọn ará Giriki sọ̀rọ̀, wọ́n ń waasu Oluwa Jesu fún wọn.

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:12-23