Ìṣe Àwọn Aposteli 11:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí ó túká nígbà inúnibíni tí ó ṣẹlẹ̀ ní àkókò Stefanu dé Fonike ní Kipru ati Antioku. Wọn kò bá ẹnikẹ́ni sọ̀rọ̀ ìyìn rere àfi àwọn Juu nìkan.

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:18-25