Ìṣe Àwọn Aposteli 11:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Agbára Oluwa hàn ninu iṣẹ́ wọn. Ọpọlọpọ eniyan ni wọ́n gbàgbọ́, tí wọ́n sì yipada sí Oluwa.

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:14-27