Ìṣe Àwọn Aposteli 11:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn aposteli ati àwọn onigbagbọ yòókù tí ó wà ní Judia gbọ́ pé àwọn tí kì í ṣe Juu náà ti gba ọ̀rọ̀ Ọlọrun.

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:1-3