Ìṣe Àwọn Aposteli 10:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó pàṣẹ pé kí wọ́n ṣe ìrìbọmi ní orúkọ Jesu Kristi. Wọ́n bá bẹ̀ ẹ́ kí ó dúró lọ́dọ̀ wọn fún ọjọ́ díẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:45-48