Ìṣe Àwọn Aposteli 11:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Peteru pada dé Jerusalẹmu, àwọn onigbagbọ tí ó jẹ́ Juu dá àríyànjiyàn sílẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ náà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:1-6