Ìṣe Àwọn Aposteli 10:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Peteru ti ń sọ̀rọ̀ báyìí lọ́wọ́, kò tíì dákẹ́ ọ̀rọ̀ tí ń sọ, bẹ́ẹ̀ ni Ẹ̀mí Mímọ́ bá bà lé gbogbo àwọn tí ó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ náà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:35-48