Ìṣe Àwọn Aposteli 10:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnu ya àwọn onigbagbọ tí wọ́n jẹ́ Juu tí wọ́n bá Peteru wá nítorí àwọn tí kì í ṣe Juu rí ẹ̀bùn Ẹ̀mí Mímọ́ gbà lọ́fẹ̀ẹ́ ati lẹ́kùn-únrẹ́rẹ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:37-48