Ìṣe Àwọn Aposteli 10:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun ni gbogbo àwọn wolii ń jẹ́rìí sí, tí wọ́n sọ pé gbogbo ẹni tí ó bá gbà á gbọ́ yóo ní ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ ní orúkọ rẹ̀.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:37-48