Ìṣe Àwọn Aposteli 10:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ mọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ ní gbogbo Judia. Ó bẹ̀rẹ̀ láti Galili lẹ́yìn ìrìbọmi tí Johanu ń sọ pé kí àwọn eniyan ṣe.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:31-38