Ìṣe Àwọn Aposteli 10:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ mọ iṣẹ́ tí ó rán sí àwọn ọmọ Israẹli, ọ̀rọ̀ ìyìn rere alaafia nípasẹ̀ Jesu Kristi, ẹni tíí ṣe Oluwa gbogbo eniyan.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:28-38